"Eleyi to maa n bi mi ninu ju laye ati ọrun ni ki wọn ti pe ẹ koo wa kọrin too ti ko elegbe ati onilu ẹ lẹyin too tun wa n fi ẹnu tun nkan ti onilu filu sọ sọ sita. Waa tun wa ko ...